Èdè

Oríṣìíríṣìí àwọn Onímọ̀ ní ó ti gbìnyànjú láti fún èdè ní oríkì tàbí òmíràn ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wònyìí, èmi pàápàá yóò gbìnyìnjú láti sọ lérèfé ohun tí èdè túmọ̀ sí. Èdè ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ báyá fún ìpolówó ọjà, ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní báyìí mo fẹ́ ṣe àgbéyẹ̀wò díẹ̀ lára àwọn onímọ̀ ti fún èdè. Gẹ́gẹ́ bí fatunsi (2001) ṣe sọ, “Language Primarily as a System of Sounds exploited for the purpose of Communication bya group of humans.” Gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ ó ní èdè jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìrú kan gbòógì tí àwùjọ àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara ẹni sọ̀rọ̀. Raji (1993:2) pàápàá ṣe àgbékalẹ̀ oríkì èdè ó ṣàlàyé wípé; “Èdè ni ariwo tí ń ti ẹnu ènìyàn jáde tó ní ìlànà. Ìkíní lè ní ìtumọ̀ kí èkeji maa ní. Èdè máa ń yàtọ̀ láti ibìkan sí òmíràn. Ohun tó fà á ni pé èdè kọ̀ọ̀kan ló ní ìwọ̀nba ìrú tó ń mú lò. Èdè kankan ló sì ní ìlànà tirẹ̀ to ń tèlé.” Wardlaugh sọ nínú Ogusiji et al (2001:10) wí pé, “Language is a System of arbitrary Vocal Symbols use for human Communication.” “Èdè ni ni àwọn àmì ìsọgbà tí ó ní ìtumọ̀ tí o yàtọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara wọn sọ̀ọ̀.” Àwọn Oríkì yìí àti ọ̀pọ̀lọpọ oríkì mìíràn ni àwọn Onímọ̀ ti gbìyànju láti fún èdè, kí a tó lè pe nǹkan ní èdè, ó gbọ́dọ̀ ní àwọn èròja wọ̀nyí: èdè gbọ́dọ̀ jẹ́:

1. Ohun tí a lè fi gbé ìrònú wa jáde

2. Ariwo tí ó ń ti ẹnu ènìyàn jáde

3. Ariwo yìí gbọ́dọ̀ ní ìtumọ̀

4. Aríwo yìí gbọ́dọ̀ ní ìlànà ìlò tí yóò ní bí a ti ṣe ń lò ó.

5. Kókó ni á ń kó ọ, kì í ṣe àmútọ̀runwá

6. nǹkan elémú-ín tó lè dàgbà sí i, tó sì lè kú ikú àìtọ́jọ́ ni èdè.

7. A lè so èdè lẹ́nu, a sì le kọ́ sìlè.

Síwájú sí í, a ní àwọn àbùdá ti èdè ènìyàn gẹ́gẹ́ bí àwọn onímọ̀ ṣe ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀. Fún àpẹẹrẹ

(1) Ìdóhùa yàtọ̀ sí ìtumọ̀ (Ar’bitransess)

(2) Àtagbà Àṣà (Cultural transmission)

(3) Agbára Ìbísí (Productivity) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lo. Gbogbo Ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn yàtọ̀ láàrín èdè ènìyàn àti ti ẹranko kì í ṣe ohun tí ó rorùn rárá. Nǹkan àkọ́kọ́ nip é a gbọ́dọ̀ wá oríkì èdè tó ń ṣiṣé lórí èyí tí a ó gbé ìpìnlè àfiwé wa lè. Ṣùgbọ́n ṣá, kò sí oríkì tí ó dàbí ẹni pé ó ṣàlàyé oríkì èdè tàbí tí ó jẹ́ ìtéwógbà fún gbogbo ènìyàn. Charles hocket ṣe àlàyé nínú Nick Cipollone eds 1994 wípé: Ọ̀nà kan gbòógì tí a fi lè borí ìṣòro yìí nip é, kí a gbìnyànjú láti ṣe ìdámọ̀ ìtúpalẹ̀ àwọn àbùdá èdè ju kí a máa gbìnyànjú láti fún ẹ̀dá rẹ̀ tí ó ṣe pàtàkì ní oríkì. Torí náà, a lè pinu bóyá èdè ẹranko pàápàá ni àwọn abida yìí pẹ̀lú… Ohun tí a mọ̀ nípa èdè ẹranko ni pé, kò só èdè ẹranko kọ̀ọ̀kan tí ó ní àwọn àbùdá èdè ènìyàn tí a ti sọ síwájú. Èyí ni ó mú kí á fẹnukò wípé àwọn èdà tí kìí ṣe àwọn ènìyàn kì í lo èdè. Dípò èdè, wọn a máa bá ara wịn sọ̀rọ̀ ní ọ̀nà tí ń pè ní ẹ̀nà, àpẹẹrẹ ìfiyèsí (Signal Cocle). Gbogbo ọ̀nà Ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn yàtọ̀ sí èyí kì í ṣe èdè. Àwọn ọ̀nà náà ní:

(1) Ìfé sísú

(2) Ojú ṣíṣẹ́

(3) Èjìká sísọ

(4) Igbe ọmọdé

(5) Imú yínyín

(6) Kíkùn ẹlẹ́dẹ̀

(7) Bíbú ti kìnnìún bú

(8) Gbígbó tí ájá ń gbó àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Gbogbo ariwo ti a kà sílẹ̀ wọ̀nyí kì í ṣe èdè nítorí pé;

(1) Wọ́n kò ṣe é fọ́ sí wẹ́wẹ́

(2) Wọn kì í yí padà

(3) Wọn kì í sì í ní Ìtumọ̀

Pẹ̀lú gbogbo àwọn nǹkan tí mo ti sọ nípa ìyàtọ̀ tó wà láàrín èdè ènìyàn àti ẹranko, Ó hàn gbangba wípé a kò le è fi èdè ẹranko àti ti ènìyàn wé ara wọn. Yorùbá bì wọ́n ní “igi ímú jìnà sí ojú, bẹ́ẹ̀ a kò leè fi ikú wé oorun. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni èdè ènìyàn àti ẹranko rí. Nínú èdè ènìyàn lati rí gbólóhùn tí ènìyàn so jáde tí a sì leè fi ìmò ẹ̀dá èdè fó sí wéwé. Àtiwípé àǹfàní káfi èdè lu èdè kò sí ní àwùjọ ẹranko gẹ́gẹ́ bí i ti ènìyàn. Fún bí àpẹẹrẹ. Olu ra ìṣu Olú nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀-Orúkọ ní ipò Olùwá, rà jẹ́ Ọ̀rọ̀-ìṣe nígbà tí ísu jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ ní ipò ààbọ̀. A kò le rí àpẹẹrẹ yìí nínú gbígbó ajá, kike ẹyẹ àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. Nítorí náà èdè ènìyàn yàtọ̀ sí enà apẹẹrẹ, ìfiyèsí (Siganl Code) àwọn ẹranko.

Àwọn ìwé ìtọ́ka sí ni àwọn wọ̀nyìí.

Fatusin, S.A (2001), An Introduction to the Phonetics and Phonology of English. Green-Field Publishers, Lagos.

Rájí, S.M (1993), Ìtúpalẹ̀ èdè àṣà lítíréṣọ̀ Yorùbá. Fountan Publications, Ibadan.

Ogunsiji, A and Akinpẹlu O (2001), Reading in English Languag and Communication Skills. Immaculate-City Publishers, Oyo.

Nic Cipollone eds (1998), Language files Ohio State University Press, Columbus.  • itokasi

Itokasi

Other Languages
Acèh: Bahsa
Afrikaans: Taal
Alemannisch: Sprache
አማርኛ: ቋንቋ
aragonés: Luengache
Ænglisc: Sprǣc
العربية: لغة
مصرى: لغه
অসমীয়া: ভাষা
asturianu: Llinguaxe
Aymar aru: Aru
azərbaycanca: Dil
تۆرکجه: دیل
Boarisch: Sproch
žemaitėška: Kalba
беларуская: Мова
беларуская (тарашкевіца)‎: Мова
भोजपुरी: भाषा
bamanankan: Kan
বাংলা: ভাষা
བོད་ཡིག: སྐད་རིགས།
brezhoneg: Yezh
bosanski: Jezik
буряад: Хэлэн
català: Llenguatge
Mìng-dĕ̤ng-ngṳ̄: Ngṳ̄-ngiòng
Cebuano: Pinulongan
Chamoru: Lengguahe
کوردی: زمان
словѣньскъ / ⰔⰎⰑⰂⰡⰐⰠⰔⰍⰟ: Ѩꙁꙑкъ
Чӑвашла: Чĕлхе
Cymraeg: Iaith
dansk: Sprog
Deutsch: Sprache
ދިވެހިބަސް: ބަސް
Ελληνικά: Γλώσσα
emiliàn e rumagnòl: Langua
English: Language
Esperanto: Lingvo
español: Lenguaje
eesti: Keel
euskara: Hizkuntza
فارسی: زبان
suomi: Kieli
føroyskt: Mál
français: Langage
arpetan: Lengoua
Nordfriisk: Spräke (iinjtål)
furlan: Lengaç
Frysk: Taal
贛語: 語言
Gàidhlig: Cànan
galego: Linguaxe
گیلکی: زوان
Avañe'ẽ: Ñe'ẽ
गोंयची कोंकणी / Gõychi Konknni: भास आनी भासविज्ञान
ગુજરાતી: ભાષા
客家語/Hak-kâ-ngî: Ngî-ngièn
עברית: שפה
हिन्दी: भाषा
Fiji Hindi: Bhasa
hrvatski: Jezik
Kreyòl ayisyen: Lang (pawòl)
magyar: Nyelv
Հայերեն: Լեզու
interlingua: Linguage
Bahasa Indonesia: Bahasa
Interlingue: Lingue
Iñupiak: Uqautchit
Ilokano: Pagsasao
ГӀалгӀай: Мотт
Ido: Linguo
íslenska: Tungumál
italiano: Linguaggio
日本語: 言語
Patois: Languij
la .lojban.: bangu
Basa Jawa: Basa
ქართული: ენა
Kongo: Ndînga
kalaallisut: Oqaatsit
ភាសាខ្មែរ: ភាសា
ಕನ್ನಡ: ಭಾಷೆ
한국어: 언어
Перем Коми: Кыв
къарачай-малкъар: Тил
Ripoarisch: Sprooch
kurdî: Ziman
коми: Кыв
kernowek: Yeth
Кыргызча: Тил
Latina: Lingua
Lëtzebuergesch: Sprooch
лезги: ЧIал
Lingua Franca Nova: Lingua
Limburgs: Taol
lumbaart: Idioma
lingála: Lokótá
ລາວ: ພາສາ
lietuvių: Kalba
latgaļu: Volūda
latviešu: Valoda
मैथिली: भाषा
Basa Banyumasan: Basa
Malagasy: Fiteny
олык марий: Йылме
Baso Minangkabau: Bahaso
македонски: Јазик
മലയാളം: ഭാഷ
монгол: Хэл
मराठी: भाषा
Bahasa Melayu: Bahasa
မြန်မာဘာသာ: ဘာသာစကား
مازِرونی: زوون
Napulitano: Lengua
Plattdüütsch: Spraak
Nedersaksies: Taol
नेपाली: भाषा
नेपाल भाषा: भाषा
Nederlands: Taal
norsk nynorsk: Språk
norsk: Språk
Novial: Lingues
Nouormand: Laungue
occitan: Lengatge
ଓଡ଼ିଆ: ଭାଷା
Ирон: Æвзаг
ਪੰਜਾਬੀ: ਭਾਸ਼ਾ
Papiamentu: Idioma
Picard: Langache
Deitsch: Schprooch
पालि: भाषा
Norfuk / Pitkern: Laenghwij
Piemontèis: Langagi
پنجابی: بولی
پښتو: ژبه
português: Linguagem
Runa Simi: Rimay
rumantsch: Lingua
Romani: Chhib
armãneashti: Limbâ
русский: Язык
русиньскый: Язык
संस्कृतम्: भाषा
саха тыла: Тыл (саҥарар)
sardu: Limbas
Scots: Leid
سنڌي: ٻولي
davvisámegiella: Giella
srpskohrvatski / српскохрватски: Jezik
සිංහල: භාෂාව
Simple English: Language
slovenčina: Jazyk (jazykoveda)
Gagana Samoa: Gagana
chiShona: Mutauro
Soomaaliga: Luuqad
српски / srpski: Језик
Sranantongo: Tongo
Sesotho: Dipuo
Seeltersk: Sproake
Basa Sunda: Basa
svenska: Språk
Kiswahili: Lugha
ślůnski: Godka
தமிழ்: மொழி
ತುಳು: ಭಾಷೆ
తెలుగు: భాష
тоҷикӣ: Забон
ไทย: ภาษา
Türkmençe: Dil
Tagalog: Wika
Tok Pisin: Tokples
Türkçe: Dil
Xitsonga: Ririmi
татарча/tatarça: Тел
українська: Мова
اردو: زبان
oʻzbekcha/ўзбекча: Til
vèneto: Łéngua
vepsän kel’: Kel'
Tiếng Việt: Ngôn ngữ
Volapük: Pük
walon: Lingaedje
Winaray: Yinaknan
Wolof: Kàllaama
吴语: 語言
isiXhosa: Ulwimi
მარგალური: ნინა
ייִדיש: שפראך
Zeêuws: Taele
中文: 語言
文言: 語言
Bân-lâm-gú: Giân-gú
粵語: 語言